Chris Oyakhilome
Ìrísí
Pastor Chris Oyakhilome | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Christian Oyakhilome 7 Oṣù Kejìlá 1963 Edo State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Pastor, faith healing minister, television host, author, philanthropist |
Gbajúmọ̀ fún | Global Evangelical Outreach |
Notable work | Founder, LoveWorld Inc |
Olólùfẹ́ | Anita Ebhodaghe (m. 1991; div. 2016) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Website | pastorchrisonline.org |
Christian Oyakhilome tí a bí ní (7 December 1963), ti a tun mọ̀ sí Pastor Chris, jẹ́ àlùfáà àti onítànilólá fún tẹlifísàn àti ààrẹ́ LoveWorld Incorporated, ẹ̀ka ìjọ́ Kristi tó wà ní ìpínlè Eko. Ó dá Christ Embassy, ijọ́ ńlá tó ní ẹ̀ka ní orílẹ̀-èdè púpọ̀, àti olùkọ̀wé ìwàásù ojoojúmọ́ Rhapsody of Realities.[1][2]
Oyakhilome tún ṣètò àwọn ìpàdé àjọyọ̀ ńlá àti "ilé-ẹ̀kọ́ ìwòsàn" rẹ̀ tó ń waye ní gbogbo ọdún ní Naijiria àti South Africa.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nwafor (25 August 2022). "Rhapsody of Realities hits 7,000 languages, hosts #ReachOutWorldLive with Pastor Chris". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 31 January 2023.
- ↑ "Pastor Oyakhilome Donates 1Billion Naira To Idahosa University". Channels Television (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 31 January 2023.
- ↑ "Thousands Attend Christ Embassy Healing School in Lagos – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 31 January 2023.