Christopher Oluwole Rotimi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Christopher Oluwole Rotimi
Governor Western State
In office
1 April 1971 – July 1975
AsíwájúRobert Adeyinka Adebayo
Arọ́pòAkin Aduwo
Ambassador of Nigeria to the United States of America
In office
March 2008 – 9 October 2009
LieutenantNull
AsíwájúGeorge Obiozor
Arọ́pòTunde Adeniran
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kejì 1935 (1935-02-20) (ọmọ ọdún 89)
Abeokuta, Ogun State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnknown
Alma materKing's College, Lagos
University College Ibadan
OccupationSoldier
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Adigun Nàìjíríà
Rank Brigadier general

Christopher Oluwole Rotimi (ọjọ́-ìbí; Ọjọ́ Ogún Oṣù Kejì, Ọdún 1935) jẹ́ Balogun àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti fẹ̀yìntì, aláṣejúṣe àti olóṣèlú, ó ṣiṣẹ́ lásìkò Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà, ó sì jẹ́ Gómìnà àwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀orùn lásìkò tí Nàìjíríà wà lábé ìjọba ológun láti ọdún 1971 sí 1975. Oluwole Rotimi di Aṣojú Nàìjíríà sí Orílẹ̀ èdè Améríkà ní ọdún 2007.[1]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Oyo State past and present. Nigeria: Ministry of Information, Youth, Sports & Culture. 2002. p. 30.