Chung Un-chan
Ìrísí
Chung Un-chan 정운찬 鄭雲燦 | |
---|---|
Prime Minister of South Korea | |
In office 29 September 2009 – 11 August 2010 | |
Ààrẹ | Lee Myung-bak |
Asíwájú | Han Seung-soo |
Arọ́pò | Yoon Jeung-hyun (Acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kejì 1948 Gongju, Korea (now South Korea) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
Alma mater | Seoul National University Miami University Princeton University |
Profession | Economist Professor |
Korean name | |
---|---|
Hangul | 정운찬 |
Revised Romanization | Jeong Un-chan |
McCune–Reischauer | Chŏng Unch'an |
Chung Un-chan (Abíi ní February 29, 1946 ní Gongju, Chungcheongnam-do, Korea Guusu) ó jẹ́ Alákoso Àgbà ilẹ̀ Korea Guusu láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n (29) Oṣù Kẹsàn-an (September)ní 2009 dé ọjọ́ kọkànlá (11) oṣù kẹjọ (Agust)(2010). Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Seoul National University láti 1978 dé2009, kí wọn ó tó yan-àn gẹ́gẹ́ bíi alákoso Àgbà, níbi tí ó ti jẹ ààrẹ yunifásítì náà láti July 2002 dè July 2006.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |