Jump to content

Lee Myung-bak

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lee Myung-bak
Hangul: 이명박
Hanja: 李明博
President of South Korea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
25 February 2008
Alákóso ÀgbàHan Seung-soo
Chung Un-chan
AsíwájúRoh Moo-hyun
Mayor of Seoul
In office
1 July 2002 – 30 June 2006
AsíwájúGoh Kun
Arọ́pòOh Se-hoon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejìlá 1941 (1941-12-19) (ọmọ ọdún 83)
Osaka, Japan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúGrand National Party
(Àwọn) olólùfẹ́Kim Yun-ok
Korean name
Hangul이명박
Revised RomanizationI Myeong-bak
McCune–ReischauerYi Myŏngpak
Pen name
Hangul일송
Revised RomanizationIlsong
McCune–ReischauerIlsong
Japanese name:
Tsukiyama Akihiro (?)

Lee Myung-bak (pípè /ˌliː ˌmjʊŋˈbæk/; Pípè ní èdè Kòréà: [i.mʲʌŋ.bak̚]; je eni ti àbí ni ojo kọkàndínlógún oṣù òpe ní ọdún 1941. Leè Myung bak gùn ó rí àga gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílè Èdè Gúúsù Korea ní ọdún 2008 ní ọjọ́ Kàrúnúndínlógbon Oṣù èrèlé . Kí ó tó di Ààrẹ orile Ede, ó kókó di baálé ìlú seoul(èyí tì ń ṣe olú ìlú Gúsù orílè-èdè Korea) láti ọjọ́ kí ní Oṣù agemo ọdún 2002 títí di ọgbọ́n ọjọ́ oṣù òkùnkùn ọdún 2006. Ó tún jé olùdarí ilé ìṣe Hyundai Engineering

Ó jẹ́ ará ẹgbẹ́ olóṣèlú Grand National Park ni ìgbà náà.