Jump to content

Coco Gauff

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Coco Gauff
Gauff at the 2022 US Open
Orílẹ̀-èdèUSA USA
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹta 2004 (2004-03-13) (ọmọ ọdún 20)
Atlanta, Georgia
Ìga1.75 m
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2018
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niCorey Gauff
Jean-Christophe Faurel[1]
Diego Moyano
Ẹ̀bùn owóUS $5,415,091 [2]
Ẹnìkan
Iye ìdíje124–62 (66.67%)
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 4 (October 24, 2022)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 7 (November 7, 2022)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà4R (2020, 2023)
Open FránsìF (2022)
Wimbledon4R (2019, 2021)
Open Amẹ́ríkàQF (2022)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2022)
Ẹniméjì
Iye ìdíje85–42 (66.93%)
Iye ife-ẹ̀yẹ6
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (August 15, 2022)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 4 (November 7, 2022)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàQF (2020, 2021)
Open FránsìF (2022)
Wimbledon3R (2021)
Open Amẹ́ríkàF (2021)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje WTARR (2022)
Grand Slam Mixed Doubles results
WimbledonSF (2022)
Open Amẹ́ríkà2R (2018)
Last updated on: January 8, 2023.

Cori "Coco" Gauff (ọjọ́ìbí March 13, 2004) ni agbá tẹnísì ará Amẹ́ríkà. Òhun ni agbá tẹnísì ọmọ-ọdún kékeré jùlọ tó wà ní top 100 lórí Women's Tennis Association (WTA), bẹ́ẹ̀sìni ipò rẹ̀ tó gajùlọ ni No. 49 lágbàayé nínú ìdíje àwọn ẹnìkan, àti ipò No. 42 nínú ìdíje àwọn ẹni méjì. Gauff gba ife-ẹ̀yẹ WTA ìdíje àwọn ẹnìkan ní 2019 Linz Open nígbà tó jẹ́ ọmọ-ọdún 15, èyí sọ ọ́ di ẹni ọjọ-orí tó kéré jùlọ tó gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje àwọn ẹnìkan lórí WTA Tour lẹ́yìn ọdún 2004. Bákannáà ó tún ti gba ife-ẹ̀yẹ méjì ìdíje àwọn ẹni méjì pẹ̀lú Caty McNally. Gauff gba òkìkí lẹ̀yìn ìgbà tó borí Venus Williams ní ayò ìfigagbága àkọ́kọ́ Wimbledon ní 2019.


  1. "How Coco Gauff compares to past tennis prodigies". ESPN.com. August 2, 2019. 
  2. "Career Prize Money Leaders" (PDF). October 31, 2022. Retrieved November 2, 2022.