Jump to content

Colin Maclaurin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Colin Maclaurin
Colin Maclaurin (1698–1746)
ÌbíFebruary, 1698
Kilmodan, Cowal, Argyllshire, Scotland
AláìsíJune 14, 1746
Edinburgh, Scotland
IbùgbéScotland
Ọmọ orílẹ̀-èdèScottish
PápáMathematician
Ilé-ẹ̀kọ́University of Aberdeen
University of Edinburgh
Ibi ẹ̀kọ́University of Glasgow
Academic advisorsRobert Simson
Notable studentsRobert Adam
Ó gbajúmọ̀ fúnEuler–Maclaurin formula
Maclaurin's inequality
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síAcadémie des Sciences, Grand Prize
Religious stancePresbyterian

Colin Maclaurin (1698 - 14 June, 1746) ni ojogbon ti o kere ju lo. omo odun mokandinlogun ni nigba ti o di ojogbom matimatiiki ni Marischa College ni Aberdeen ni Scotland ni Ogbon-ojo osu kesan-an odun 1717. Leyin eyi ni o lo di ojogbon Matimatiiki ni Edinburgh ni scotland ni 1725. Sir Isaac Newton ni o ni ki won so o di ojogbon nibe.