Comfort Ekpo
Comfort Ekpo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ Kejìlá oṣù kọkànlá ọdun 1954 Uyo, Ìpínlè Akwa Ibom |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Vice Chancellor |
Comfort Ekpo listen (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kọkànlá ọdun 1954) jẹ́ Ọ̀mọ̀wé ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ti fi ìgbàkan jẹ́ adarí Yunifásitì ìlú Uyo.
Ìtàn ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Comfort Memfin Ekpo ní Uyo ní ọdun 1954. Àwọn òbí rẹ̀ ni Etim Udoh Isok àti Nyong Sam Akpan. Comfort ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olùkọ́ Sunday School teacher àti gẹ́gẹ́ bi ẹni tí ó ń ran olùkó lọ́wọ́ ní Yunifásítì ìpínlè Cross River láàrin ọdun 1983 sí 1991.[1]
Ekpo ti fi ìgbàkan jẹ́ adarí Yunifásítì ìlú Uyo , òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di ipò adarí Yunifásitì náà mú.[2] Ní oṣù Kejìlá ọdun 2015, wọ́n yan ọ̀jọ̀gbọ́n Enefiok Essien láti rọ́pò rẹ̀ ṣùgbọ́n ó kọ̀wé sí Mínísítà ètò ẹ̀kọ́, Adamu Adamu láti mú ìfàsẹ́yìn bá àbá láti yàn sípò náà. Ó kọ̀wé yìí látàrí èsùn ìbáni ṣe ìranù àtilèsùn yí yí ìwé tíeàwọn oníròyìn fi sun Essienthe press.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Professor (Mrs) Comfort Memfin Ekpo BLS, Ed. M.Ed. Ph.D.". Universal Learning Solutions (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-02-26. Retrieved 2020-05-02.
- ↑ Leading Women[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], 2014, SunNewsOnline.com, Retrieved 8 February 2016
- ↑ UNIUYO VC asks education minister to suspend appointment of professor indicted for sexual assault, December 2015, Premium Times NG, Retrieved 8 February 2016