Daniel Bernoulli

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Daniel Bernoulli
Daniel Bernoulli
Ìbí8 February 1700
Groningen, Netherlands
Aláìsí8 March 1782 (aged 82)
Basel, Switzerland
Ibùgbéunknown
Ó gbajúmọ̀ fúnBernoulli's Principle, early Kinetic theory of gases, Thermodynamics
Religious stanceCalvinist
Signature

Daniel Bernoulli (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù kejì odun 1700, ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kẹjọ oṣù Kẹta ọdún 1782) jẹ́ ògbóǹtarìgì onímọ̀ Ìṣirò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Dutch-Swiss mathematician, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ògbóǹtarìgì onímọ̀ Ìṣirò tí ẹbí Bernoulli.[1] [2]



Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Swiss mathematician". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-12-16. 
  2. "Daniel Bernoulli". Encyclopedia.com. 2019-12-10. Retrieved 2019-12-16.