Jump to content

Johann Bernoulli

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Johann Bernoulli
Johann Bernoulli
Ìbí(1667-07-27)27 Oṣù Keje 1667
Basel, Switzerland
Aláìsí1 January 1748(1748-01-01) (ọmọ ọdún 80)
Basel, Switzerland
IbùgbéSwitzerland
Ọmọ orílẹ̀-èdèSwiss
PápáMathematician
Ilé-ẹ̀kọ́University of Groningen
University of Basel
Ibi ẹ̀kọ́University of Basel
Doctoral advisorJacob Bernoulli
Doctoral studentsDaniel Bernoulli
Leonhard Euler
Johann Samuel König
Pierre Louis Maupertuis
Ó gbajúmọ̀ fúnDevelopment of infinitesimal calculus
Catenary solution
Bernoulli's rule
Bernoulli's identity
Religious stanceCalvinist
Notes
Brother of Jakob Bernoulli, and the father of Daniel Bernoulli.

Johann Bernoulli (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1667, ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1748)[1] jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Swiss onímọ̀ Ìṣirò àti ọ̀kan nínú àwọn onímọ̀ Ìṣirò pàtàkì nínú ẹbí Bernoulli. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ sí kalkulosi ikerelailopin, ó sì kọ́ Leonhard Euler lẹ́kọ̀ọ́ nígbà èwe rẹ̀.[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Johann Bernoulli (1667 - 1748)". MacTutor History of Mathematics. Retrieved 2019-12-16. 
  2. "Swiss mathematician". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-12-16.