Dauda Soroye Adegbenro
Ìrísí
Alhaji Olóyè Dauda Soroye Adegbenro (1909 - 1975) jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Naijiria to jẹ mínísítà fún ọrọ ilẹ pẹlu iṣẹ atí adari orilẹ-ède ti ẹgbẹ Action Group (AG).[1]
Ìpele ìbẹrẹ ti igbesi ayé rẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún 1909 ni wọ́n bí Adegbenro ní Ago-Owu, Abéòkúta, ìpínlẹ̀ Ògùn.[2] Dauda Soroye Adegbenro lọ sí ileewe African School, Owowo fún ètò ẹkọ alakọbẹrẹ ko to lọ sí Baptist Boys High School, Abéòkúta àti Abeokuta Grammar School fún ẹkọ gírámà.
Bí o ṣe gbà ṣiṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àjọ Nigeria Railway Corporation gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé láti ọdún 1930 sí 1937. Lẹ́yìn ìyẹn, ó ṣiṣẹ́ olùtọ́jú ilé ìtajà pẹ̀lú United African Company.[3]
Àwọn itọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Toyin., Falola (2009). Historical dictionary of Nigeria. Genova, Ann.. Lanham, Md.: Scarecrow Press. ISBN 9780810856158. OCLC 310171807.
- ↑ "D.S. Adegbenro: The Owu-born Premier of Western region".
- ↑ "Adegbenro Dauda Soroye". Litcaf. 2016-01-22. Archived from the original on 2021-04-27. Retrieved 2021-04-27.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |