Davidi oba
Ìrísí
Davidi, gẹ́gẹ́ bí Bíbélì ti sọ ni ọba kẹta ìjọba àpapò Isreali. [1][2] Awon ìwé Sámúẹ́lì sọ nipa ti Davidi pé ó jẹ́ ó domo kùnrin olùsọ́ agutan ẹni tí ó gbajugbaja lẹ́yìn ìgbà tí ó pa Goliati, jagunjagun alágbára ará Filisteni ní is gúúsù àti Canani. Èyí mú kí Saalu féràn Davidi, Davidi sì tún di ọ̀rẹ́ Jónátánì ọmọ Saalu. Ṣùgbọ́n nígbà tí Saalu woye pé Davidi le dé ipò ọba, ó gbìyànjú láti pá.,èyí mú kí Davidi ó sá fún èmi tí ó sì fara pamo fún ọ̀pọ̀ ìgbà. Léyìn ìgbà tí wọ́n pa Saalu àti Jónátán lójú ogun, a yan Davidi(ẹni tí ó jẹ́ omo ọdun ọgbọ̀n nígbà náà) gẹ́gẹ́ bi ọba gbogbo Isreali àti Júdà.
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Carr, David M. (2011). An Introduction to the Old Testament: Sacred Texts and Imperial Contexts of the Hebrew Bible. John Wiley & Sons. p. 58. ISBN 978-1-44435623-6. https://books.google.com/books?id=OzHhuvuEQxQC&pg=PA58. Retrieved 2020-10-05.
- ↑ Falk, Avner (1996). A Psychoanalytic History of the Jews. Fairleigh Dickinson University Press. p. 115. ISBN 978-0-83863660-2. https://books.google.com/books?id=z10-Xz9Kno4C&pg=PA115. Retrieved 2020-10-04.