Bíbélì Mímọ́
Kini Bibeli? (Bibeli Mimo)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Bíbélì Mímọ́, tabi Bíbélì jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn ìwé Ẹ̀sìn Ju àti Ẹ̀sìn Kristi.[1][2]
Bibeli Heberu tabi Bibeli Awon Ju da si apa meta:
- Torah, tabi "Ilana" ti a mo si Pentatefki tabi "Iwe Marun Mósè"
- Nefimu, tabi "Awon Woli"
- Ketufimu, "Akole mimo"

Bibeli awon Ẹlẹ́sìn Kristi da si apa meji.
Ni Bibeli awa ni awon iwe 66. Oluwa-Olorun ti lo opolopo èniyàn dabi Mose, Solomoni, Samueli, ati Aposteli Paulu lati ko Bibeli. Èniyàn, won ti n wa laaye ni orisirisi akoko, sugbon lapapo, Oluwa-Olorun ti lo lati ko ohun ti awa mo bi Bibeli (Bibeli Mimo)!
Apa Kinni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Apa Keji
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kini Ọ̀run? Tabi Ijoba Ọ̀run?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọ̀run tabi Ijoba Ọ̀run je ijoba Olorun. Nibo awa ni opolopo angeli, ayo, ohun ti dara. Ni Ijoba Orun, awa n ko ku, awa korin si Olorun, ati awa n wa laaye titi làélàé. Ijoba Ọ̀run ti dara gidigidi.
Kini Awon Angeli?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon Angeli wa iranse Olorun, won sise fun Olorun ati won wa dara. Saamu 34:7 so pé «7Angẹli Olúwa yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká
ó sì gbà wọ́n.»
Kini Orun-apaadi?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orun-apaadi je ilé Bìlisì. Ni Orun-apaadi, ko si ayo, ko si kankan dara. Ina je ni Orun-apaadi, Ina ainipèkun.
Marku 9:43-48
43Bí ọwọ́ rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, gé e sọnù, ó sàn fún ọ kí o ṣe akéwọ́ lọ sí ibi ìyè, ju o ní ọwọ́ méjèèjì kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì, sínú iná àjóòkú. 44Níbi tí kòkòrò wọn kì í kú tí iná nà án kì í kú. 45Bí ẹsẹ̀ rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, gé é sọnù, ó sàn kí ó di akesẹ̀, kí o sì gbé títí ayé àìnípẹ̀kun ju kí o ní ẹsẹ̀ méjì tí ó gbé ọ lọ sí ọ̀run àpáàdì. 46Níbi tí kòkòrò wọn kì í kú, tí iná nà án kì í sì í ku. 47Bí ojú rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì. 48Níbi ti
“ ‘kòkòrò wọn kì í kú,
tí iná kì í sì í kú.’
Tani Bìlisì tabi Emi Esu?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bìlisì je Emi Esu, o je buburu gidigan ati je ota ti Olorun wa. Ibi-afede re je lati «jalè, láti pa, àti láti parun:» Bìlisì fe pé gbogbo èniyàn ma losi Orun-apaadi, ki i se Ijoba Orun.

Kini awon Ànjọ̀nú?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon Ànjònu wa ore Bìlisì, ati won ni ife okan, won sise pelu Bìlisì lati «jalè, láti pa, àti láti parun:»
Kini ẹ̀ṣẹ̀?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]ẹ̀ṣẹ̀ je ohun buburu. Ti awa ba n se kankan ti awa n mo pé, ko dara, o je ẹ̀ṣẹ̀. E jo, e maa se e.
Johanu 8:34 «34 Jesu dá wọn lóhùn pé, “Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń dẹ́ṣẹ̀, ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ ni.»[3]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "What is the Bible?". Bible Society New Zealand. 2022-07-19. Retrieved 2022-12-04.
- ↑ "The Bible". HISTORY. 2018-01-19. Retrieved 2022-12-04.
- ↑ https://www.bible.com/bible/911/JHN.8.YCB