Ìwé Dẹutẹ́rónómì
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ìwé Deuteronomi)
Ìwé Deutẹ́rómómì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa irúfẹ́ ìṣẹ̀dá Ọlọ́run bí Ó ṣe tóbi tó, àti àwọn èrè ẹ̀ṣẹ̀ fún ẹni tó bá lòdì sí àwọn òfin àti ìlànà rẹ̀. Ìwé yìí tún sọ̀rọ̀ nípa àwọn aláìní àti ipò tí kò tẹ́rùn tí wọ́n wà nínú àwùjọ. Abbl.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |