Ìwé Ẹkún Jeremíàh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jeremáyà Nínú Ìrònú.

Ìwé Ẹkún Jeremáyà jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa ìtìjú, ìjìyà, àti ìdààmú Jerúsálẹ́mù àti àwọn ènìyàn rẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ará Bábílónì pa ìlú wọn run.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]