Májẹ̀mú Titun
Appearance
Majẹmu titun[note 1] ni ìpín kejì tí Bíbélì mímọ Kristẹni. Ó sọ nípa àwọn ẹ̀kọ́ àti ìgbẹ́ ayé Jesu,o tún sọ nípa ìgbé ayé àwọn Kristẹni.
Májẹ̀mú titun jẹ́ àpapọ̀ àwọn ìwé Kristẹni tí wón ko ní èdè Griki, oríṣi àwọn ènìyàn mimo ni ó ko àwọn ìwé yìí. Majẹmu titun ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjọ jẹ́ àpapọ̀ ìwé metadinlogbon.
- Àwọn ìwé Ìhìn réré mẹ́rin(Mátíù, Maru, Lúùkù àti Jòhánù).
- Ìwé ìṣe àwọn Àpọ́sítélì
- Àwọn ìwé mẹ́tàlá Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù
- Ìwé sí àwọn Hébérù
- 7 Àwọn ìwé méje sí àwọn Kristẹni
- Ìwé ìfihàn.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/>
tag was found