Jump to content

Ìwé àwọn Oníwàsù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìwé àwọn Oníwàásù.

Ìwé àwọn Oníwàásù jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa ìdùnnú níní nínú àwọn tí a ò fi bẹ́ẹ̀ kà kún, bí i oúnjẹ jíjẹ àti mímú. Bẹ́ẹ̀ kí a má rí ìdùnnú nínú iṣẹ́ wá. Ìwé yìí tún sọ̀rọ̀ nípa àkókò ṣe wà fún gbogbo ohunkóhun, àti ṣe kókó tó.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]