Jump to content

Ìwé Hóséà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ìwé Hosea)
Ìwé Hóṣéà.

Ìwé Hóṣéà jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó ń ṣàfiwé ìfẹ́ Hóṣéà sí aya rẹ̀ tó dẹ́ṣẹ̀ àgbèrè, tí ó ṣì fẹ́ràn tó sì gbà tọwọ́-tẹsẹ̀ padà. Tí ó sì jẹ́ wí pé, ní tòótọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì apá àríwá Jerúsálẹ́mù ní ọ̀rọ̀ náà ń pàrọwà sí pé àánú Ọlọ́run ń bẹ láti gbàlà, ràpadà, túnṣe àti fẹ́ gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ káàkiri wà títí tí wọ́n bá tan orísun wọn padà sí i.