Jump to content

Ìwé Ẹ́srà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ìwé Ẹsra)
Ìwé Ẹ́sírà.

Ìwé Ẹ́sírà jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa ìpadà ìránṣẹ́ Ọlọ́run, àti àwọn ọwọ́ Júù méjì kan láti Bábílónì padà sí Jerúsálẹ́mù, níbi tí wọ́n ti tún àwùjọ wọn kọ́ padà sí. Ó tún sọ̀rọ̀ nípa bí i Ọlọ́run ṣe ran àwọn ọmọ rẹ̀ tàbí àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́ borí àwọn ọ̀tá wọn, láti mú ìlérí Rẹ̀ ṣe sí wọn.