Delphe Kifouani
Ìrísí
Delphe Kifouani jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Kóngò. Ó maá n ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní ìmọ̀ sinimá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Saint-Louis, èyí tí ó wà níSẹ̀nẹ̀gàl.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Delphe Kinouani, africultures.com