Derek Bentley case
Derek William Bentley (30 Osu kefa Ọdun 1933 – 28 Oṣu Kini Ọdun 1953) jẹ ọkunrin ara ilu Gẹẹsi kan ti a pa nipa siso o ro titi emi fi bo ni enu re fun ipaniyan ọlọpa kan lakoko igbiyanju idigun jale kan. Christopher Craig, ẹni ọdun mokan din l'ogun ti o je ọrẹ ati alabaṣiṣẹpọ Bentley, ni a fi ẹsun ipaniyan naa kan. Bentley fi idi re mule wipe Bentley jẹbi ẹsun kikopa ninu itapa si ofin naa, nipasẹ ilana ofin kan ninu iwe ofin ile Gẹẹsi ti a mo si “ ifọwọsowọpọ ”, nitori wipe iwa idigun jale yi ni a se pelu isokan. Idajo naa ko wa ni isokan.
Awọn igbimo idajo ti a gbe kale fi idi re mule wipe Bentley jẹbi esun ti a fi kann lori itumo ti agbejoro ijoba fun oro kan ti Bentley so wipe "Jẹ ki o gbaa" (iyanju ti Bentley fun Craig), ti a ko si le fi itumo re lele ni pato tabi idaniloju leyin ti onidajọ.Oloye Goddard, ti ṣe apejuwe Bentley gẹgẹbi "eni ti o se iranlọwọ ọpọlọ ninu ipaniyan Sidney Miles".Goddard ṣe idajọ iku fun Bentley nipa siso ro titi ti emi yi o fi bo ni enu re lai bikita fun idirebe awon igbimo idajo lati dari ji arakunrin naa: Labẹ Idajọ ti Ofin Iku 1823, ko si idajo miiran ti o ṣee ṣe (biotilejepe Ofin ipaniyan 1957, eyiti o ṣafihan awọn aabo ojuse ti o din(biotilejepe Ofin ipaniyan 1957, eyiti o ṣafihan awọn aabo ojuse ti o dinku ti o lagbara, ti fẹrẹẹ jẹ ipa nipasẹ ejo Bentley yi).
Ẹjọ Bentley yi di mimo kaakiri ilu ti o fi je wipe o yori si ipolongo ọdun marun din laadota lati gba idariji fun Derek Bentley lẹhin iku re, eyiti o di sise ni ọdun 1993, pelu ipolongo lati pa ejo iku ti pa ejo iku ti a da fun rẹ, eyiti o waye ni ọdun 1998. Nitoribẹẹ ọran rẹ yi ni a ka si ọran ti ilodi si idajọ pelu ejo ti Timothy Evans, eyi ti o si je idi kan pataki ninu aṣeyọri ipolongo lati fopin si ijiya iku ni ile Geesi .
Ibere Igbesi aye re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Derek Bentley wo ile iwe Norbury Manor Secondary Modern School ni odun 1944.leyin igba ti o ti idi r'emi ninu idanwo awon omo odun mokanla soke. Ki o to pari ninu osu March,odun 1948,Bentley ati omodekunrin kan ni a awon olopa fi kele ofin gbe fun esun ole. Leyin osu mefa, a da won lejo lati lo se ewon odun meta ni Kingswood Approved School,leba Bristol.Christopher Craig naa je akeko ni ile iwe Secondary Modern school yi.
Ilera ati idagbasoke ti opolo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Derek Bentley ni opolopo awọn iṣoro idagbasoke ilera. Awọn obi rẹ royin wipe ninu ijamba kekere kan ni o ti fọ imu rẹ ati wipe lati naa naa o ni ijagba mẹta, okan ninu eyiti wọn sọ pe o fẹrẹ gba emi re. Ebi naa tun sọ wipe emeta otooto ni a fi ado oloro le won jade lakoko Ogun Agbaye II, ati wipe ninu ọkan ninu awọn iṣẹlẹ wọnyi, ile ti o ngbe wó moo lori, ṣugbọn ile-ẹjọ ko rii itọkasi kanka wipe o fi ara pa naa. [1] :102
A ran Bentley lo si Ile-iwe Ikẹkọ Kingwood, Bristol ni ọjọ keta din logbon, Oṣu Kẹwa Ọdun 1948. Wọ́n ṣe àyẹ̀wò fún un ní asiko to fi í s'ẹ́wọ̀n níbẹ̀. Ni Oṣu Kejila ọdun 1948 (nigbati o jẹ ọmọ ọdun Meedogun ati abo), ọjọ ori ọpọlọ rẹ ni koju ti omo ọdun mewa ati oṣu mẹrin lo, nigbati o gba 66 ninu opolo kan. Awọn oṣiṣẹ Kingwood royin pe o jẹ “ọlẹ, alaibikita, olufokansi ati ti iru 'alarekereke eniyan'”, ti ile-ẹjọ si ṣe apejuwe rẹ gẹgẹbi “alaibikita, eni ti nkan ko jo loju, ati eni ti o setan lati sọ awọn itan”. Lẹhin igba i a fi kele ofin gbe ni Oṣu kọkanla ọdun 1952, a tun se awọn idanwo opolo fun u ni ogba ewọn Brixton . Ibi ni a ti se apejuwe re geg bi "eni ti ko ni oye", ti o si ni akosile 71 ninu oro siso,87 ninu ise sise ati akojopo akosile ninu idanwo opolo ti o je 77.
A ṣe awari pe o tun jẹ “ alaimọwe pupọ” ni akoko ti a munn ni Oṣu kọkanla ọdun 1952. Awon oṣiṣẹ ilera ninu ogba ewon sọ wipe “ko le ṣe idanimọ tabi kọ gbogbo awọn lẹta ti alfabeti silẹ”.
- ↑ Murder in Cold Blood ISBN 1-871-61216-0