Diahann Carroll
Appearance
Diahann Carroll | |
---|---|
Carroll in 1976 | |
Ọjọ́ìbí | Carol Diahann Johnson Oṣù Keje 17, 1935 Bronx, New York, U.S. |
Aláìsí | October 4, 2019 Los Angeles, California, U.S. | (ọmọ ọdún 84)
Ẹ̀kọ́ | Music & Art High School |
Iléẹ̀kọ́ gíga | New York University |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1950–2015 |
Ọmọ ìlú | Harlem, New York, U.S.[1][2] |
Olólùfẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ | Sidney Poitier (1959–1968) David Frost (1970–1973) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | 1969 Golden Globe Award for Best TV Star – Julia |
Diahann Carroll ( /daɪˈæn/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Carol Diann Johnson; July 17, 1935 – October 4, 2019)[2] jẹ́ òṣèré., akọrin, aláṣọ-oge ati alákitiyan ará Amẹ́ríkà. Ó kọ́kọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká láti inú àwọn fíìmù tó ní òṣèré aláwọ̀-dúdú nínú bíi Carmen Jones (1954) àti Porgy and Bess (1959). Ní ọdún 1962, Carroll gba Ẹ̀bùn Tony bí òṣèré obìnrin tó dára jùlọ, obìnrin aláwọ̀-dúdú àkọ́kọ́,fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré orí-ìtàgé Broadway nípa kíkọ orin No Strings.
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ New York Times - AN APPRAISAL - Diahann Carroll, Indelible Fixture of My Childhood - Ms. Carroll was part of my extended family, that fabulous aunt who commanded attention by simply walking into the room, by Pierre-Antoine Louis. October 6, 2019
- ↑ 2.0 2.1 NBC News – Diahann Carroll, first black woman to star in nonservant role in TV series, dies at 84 – Carroll was the star of "Julia," which ran for 86 episodes on NBC from 1968 to 1971. By David K. Li and Diana Dasrath, October 4, 2019