Sidney Poitier

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Sidney Poitier

Sidney Poitier, August 28, 1963
Ìbí Oṣù Kejì 20, 1927 (1927-02-20) (ọmọ ọdún 90)
Miami, Florida, U.S.
Iṣẹ́ Actor, director, writer, diplomat
(Àwọn) ìyàwó Juanita Hardy (1950-1965)
Joanna Shimkus (1976-present)

Sidney Poitier, KBE (pípè /ˈpwɑːtjeɪ/ or /ˈpwɑːti.eɪ/; ojoibi February 20, 1927) je osere, oludari filmu, adawe ati diplomati ara Amerika ti awon obi re wa lati orile-ede Awon Bahama.

Ni 1963, Poitier di adulawo akoko to gba Ebun Akademi fun Osere Okunrin Didarajulo[1] fun isere re ninu Lilies of the Field.[2] Bi ebun yi se se pataki to han kedere ni 1967 nigba to lewaju ninu awon filmu meta ti won yori si rere—To Sir, with Love; In the Heat of the Night; ati Guess Who's Coming to Dinner—ti won so di osere to pawo julo ni odun na.[3] Ni 1999, American Film Institute pe Poitier pe o wa larin awon osere olokiki julo lailai, ni ipo 22k larin awon 25.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]