Denzel Washington

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Denzel Washington
at press conference for The Hurricane, 2000 Berlinale.
ÌbíDenzel Hayes Washington, Jr.
28 Oṣù Kejìlá 1954 (1954-12-28) (ọmọ ọdún 69)
Mt. Vernon, New York,
United States
Iṣẹ́Actor, screenwriter, director, producer
Awọn ọdún àgbéṣe1977–present
(Àwọn) ìyàwóPauletta Pearson (1983-present)

Denzel Hayes Washington, Jr. (ọjọ́ ìbí Ọ̣jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1954) jẹ́ òṣèré àti olùdarí eré ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Washington ti gba ẹ̀bùn Oscar àti ẹ̀bùn Wúrà Róbótó ní ẹ̀méèjì.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]