Jump to content

Sean Penn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sean Penn
Penn at the premiere for Milk at the Castro Theatre, San Francisco, October 2008
Aṣojú-níbi-gbogbo fún Haiti
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 31, 2012
ÀàrẹMichel Martelly
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Sean Justin Penn

17 Oṣù Kẹjọ 1960 (1960-08-17) (ọmọ ọdún 64)
Los Angeles County, California, U.S.
Ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
(Àwọn) olólùfẹ́Madonna (1985–1989)
Robin Wright (1996–2010)
ẸbíAimee Mann (sister-in-law),
Leo Penn (father),
Eileen Ryan (mother),
Chris Penn (brother),
Michael Penn (brother)
Àwọn ọmọ1 son,
1 daughter
Àwọn òbíLeo Penn (deceased)
Eileen Ryan
ResidenceLos Angeles, California
Alma materSanta Monica College
OccupationActor, screenwriter, director, producer
AwardsAcademy Award, Golden Globe, Screen Actors Guild Award, Christopher Reeve First Amendment Award

Sean Justin Penn (ojoibi August 17, 1960) ni osere, olukoweitage ati oludari filmu ara Amerika, o tun gbajumo fun isakitiyan alawujo ati oloselu egbeowo-osi re (pelu ise omoniyan). O gba Ebun Akademi ni emeji fun ere to se niu filmu Mystic River (2003) ati Milk (2008), beeni bakanna o tun gba Ebun Wura Roboto fun filmu akoko ati Ebun Egbe awon Osere Ojuworan fun ekeji.