Dolly Unachukwu
Ìrísí
Dolly Unachukwu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Dolly Nchedo Nkem Unachukwu 1 Oṣù Kọkànlá 1969 Lagos, Nigeria |
Iṣẹ́ | Actress, writer, producer, film director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1986 - present |
Olólùfẹ́ | Emmanuel Nwokenkwo (1992 - 1994) (divorced) 1 child Jonathan Ezea (2000 - 2000) (annulled) Dr. Olaniyan (2011-present) [1] |
Dolly Unachukwu (tí a bí ní 1 Kọkànlá Oṣù 1969) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, agbéréjáde, ònkọ̀wé, àti olùdarí. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹni-ìṣáájú ti Nollywood. Ó gbajúmọ̀ káárí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bi Fadake Akin-Thomas nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Fortunes.[2]
A bí Dolly Unachukwu ní ọdún 1969 sí ìdílé eléyàn méje kan. Unachukwu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìndínlógún. Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Amichi ní Ìpínlẹ̀ Anámbra.
Àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ nínu eré wáyé ní ọdún 1985 níbi tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé. Lẹ́yìnwá ìgbà náà ló kópa nínu eré Mirror in the Sun gẹ́gẹ́ bi Prisca.
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Mirror in the Sun (TV) 1986
- Fortunes (TV) 1993
- Deadly Affair 1995 1&2 1994
- Glamour Girls 2 1995
- Tears for Love 1996
- Deadly Affair II 1997
- Deadly Passion 1997
- Wildest Dream 1997
- Love without Language 1998
- Brotherhood of Darkness 1998
- Father Moses 1999
- Full Moon 1 & 2 1999
- War of Roses 2000
- The Empire 2005
- Sisters Love 2007
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Dolly Unachukwu weds third husband". Vanguard. 2011-05-14. http://www.vanguardngr.com/2011/05/dolly-unachukwu-weds-third-husband/. Retrieved 2012-03-04.
- ↑ e 20