Dr. Dre

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dr. Dre
Dr. Dre backstage at a concert in 2008
Dr. Dre backstage at a concert in 2008
Background information
Orúkọ àbísọAndre Romelle Young[1]
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kejì 1965 (1965-02-18) (ọmọ ọdún 59)
Compton, California, U.S.
Ìbẹ̀rẹ̀Los Angeles, California,
U.S.
Irú orinHip hop, Gangsta Rap
Occupation(s)Record producer, rapper, entrepreneur
InstrumentsVocals, synthesizer, keyboards, turntables, drum machine, sampler
Years active1983–present
LabelsPriority, Death Row, Aftermath, Interscope, Ruthless
Associated actsWorld Class Wreckin' Cru, N.W.A, Ice Cube, Snoop Dogg, Xzibit, 2Pac, Eminem, 50 Cent, Game
Websitedrdre.com

Andre Romelle Young tí a bí ní ọjọ́ Kejì dín lógún, oṣù Kejì, ọdún 1965 tí ó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ ńjẹ́ Dr. Dre, jẹ́ atọ́kùn àwo orin, [[rapper| afọ̀rọ̀dárà, onígbọ̀wọ́ àwo orin, oníṣòwò, àti lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan bíi òṣèré ará Amẹ́ríkà . Òun ni Olùdásílẹ̀ àti ọ̀gá àgbà Aftermath Entertainment bẹ́ẹ̀ sì ni ó ji fi ìgbà kan rí jẹ́ je onígbọ̀wọ́ fún Death Row Records. Ó ti ṣe olóòtú àwo orin púpọ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn afọ̀rọ̀orindárà ni wọ́n wá láti Ilé-iṣẹ́ rẹ́kọ̀ọ̀dù rẹ̀, àwọn bí i Snoop Dogg, Eminem àti 50 Cent. Gégébí olóòtú àwo orin, ó jẹ́ ẹnìkan pàtàkì tí ó jẹ́ kí orin G-funk West Coast ó gbajúmọ̀.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ro 2007, p. 1