Jump to content

Dr Gab

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olùkọ́ni ilé ẹ̀kọ́ gíga, LASU
Ganiu Abisoye Bamgbose

Dr Ganiu Abisoye Bamgbose (Dr GAB) jẹ ọmọ Naijiria, ọ̀mọ̀wé ati oniwadi. Lọwọlọwọ ó jẹ́ olùkọ́ni ni Ẹka Gẹẹsi, Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Èkó, Nàìjíríà.

Ganiu Abisoye Bamgbose
àrẹọ̀nà kakanfò àwọn gabians
Ọjọ́ìbíGaniu Abisoye
Èkó, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Olùkọ́ni ilé ẹ̀kọ́ gíga

Ganiu ni PhD kan ni Gẹẹsi ati pé ó ti ṣe àtẹ̀jáde méjèèjì ni àwọn ìwé agbègbè yìí àti ti káríayé nínú ẹ̀ka ìmọ̀ èdè (linguistics). Ó sì ti dásí àwọn ọ̀rọ̀ ti àyíká ẹ̀kọ́, òṣèlú, ìbáraẹnilò ati àṣà tí ó gbajúmọ̀ pèlú àlàyé tí ó kúnná nínú sísọ nípa wọn. Àwọn ìwádìí tí ó nífẹ̀ sí rèé ṣùgbọ́n kò pin si: Pragmatics, (pataki) àtúpalẹ̀ ọ̀rọ̀, gírámà Gẹ̀ẹ́sì, ìmọ̀-ọ̀rọ̀ àwùjọ tí ó jẹ́ mọ́ àṣà àti èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Nàìjíríà.