Eartha Kitt

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eartha Kitt
Kitt performing in concert, 2007
Ọjọ́ìbíEartha Mae Keith
(1927-01-17)Oṣù Kínní 17, 1927
North or St. Matthews, South Carolina, U.S.
AláìsíDecember 25, 2008(2008-12-25) (ọmọ ọdún 81)
Weston, Connecticut, U.S.
Orúkọ mírànMiss Kitt, Mother Eartha,[1] Kitty
Iṣẹ́
  • Singer
  • actress
  • dancer
  • activist
  • comedian
  • author
  • songwriter
Ìgbà iṣẹ́1942–2008
Olólùfẹ́
John W. McDonald
(m. 1960; div. 1965)
Àwọn ọmọ1
Websiteearthakitt.com
Musical career
Irú orin
Labels
Associated acts

Eartha Kitt (ọjọ́ìbí Eartha Mae Keith; January 17, 1927 – December 25, 2008) jẹ́ akọrin, òṣeré, oníjó, aláwàdà, alákitiyan, olùkòwé àti akọ̀wé-orin ará Amẹ́ríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ọ̀nà ìkọrin rẹ̀ àti àwọn orin rẹ̀ bíi "C'est si bon" àti "Santa Baby", àwọn orin yìí dé top 10 lórí Billboard Hot 100. Orson Welles pe Eartha Kitt ní "obìnrin tó wuyì jùlọ lágbàáyé".[2]

Kitt bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 1942 ó sì kópa nínú eré tíátà tó únjẹ́ Carib Song. Ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1950, ó gbé orin jáde tí nínú wọn jẹ́ "Uska Dara" àtid "I Want to Be Evil". Àwọn orin rẹ̀ míràn tún ni "Under the Bridges of Paris" (1954), "Just an Old Fashioned Girl" (1956) àti "Where Is My Man" (1983). Ní ọdún 1967 ó ṣeré bíi Catwoman, nínú eré orí tẹlifísàn Batman.

Ní ọdún 1968, iṣẹ́ rẹ̀ ní Amẹ́ríkà rẹlẹ̀ lẹ̀yìn ìgbà tó lòdì sí Ogun Vietnam nínú ọ̀rọ̀ tó sọ ní ibi àjọyọ ní White House. Ọdún mẹ́wàá lẹ́yìn náà, ó padà sí ṣeré nínú eré ìtàgé tó ṣe ní ọdún 1978 tó únjẹ́ Timbuktu!, èyì tó gba ìkan nínú àwọn ìpèlórúkọ méjì Ẹ̀bùn Tony fún. Ìpè kejì fún Ẹ̀bùn Tony ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2000 fún The Wild Party. Kitt kọ ìwé-ìgbésíayé araẹni mẹ́ta.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Mother Eartha" Archived 2014-01-01 at the Wayback Machine.. Philadelphia City Paper. January 17–24, 2002. Retrieved October 9, 2013.
  2. Messer, Kate X. (July 21, 2006). "Just An Old Fashioned Cat". The Austin Chronicle. http://www.austinchronicle.com/arts/2006-07-21/388422/. 
  3. Kitt, Eartha (1990). I'm Still Here. London: Pan. ISBN 0-330-31439-4. OCLC 24719847.