Ìlaòrùn Áfríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti East Africa)
Jump to navigation Jump to search
LocationEasternAfrica.png

Iha tabi Apa Ilaoorun Africa jé ïhà tó sumo apa ilà oòrùn jù, àwon orílè-ede tówà ní ìlà-oòrùn Afrika ní: Tanzania, Kenya, Uganda, Rwanda, Burundi, Eritrea,Ethiopia, Somalia, Comoros, Mauritius, Seychelles, Sudan, Djibouti, Eritrea, Madagascar, Malawi, Réunion, Somaliland, Ìlà-oòrùn Afrika ní olùgbé to sumó 464,911,091 ni 2022 [1]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Population of Eastern Africa (2022)". Worldometer. 2022-03-24. Retrieved 2022-03-25.