Jump to content

Èbúté-Èrò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ebute Ero)

Àdàkọ:Use Nigerian English

Èbúté-Èrò
Town
Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913)
Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913)
Èbúté-Èrò is located in Nigeria
Èbúté-Èrò
Èbúté-Èrò
Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750
Country Nigeria
StateÌpínlẹ̀ Èkó
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ebúté Èrò jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Lagos IslandÌpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1] Èbúté Èrò jẹ́ ìlú ńlá tí ó gbajúmọ̀, tí ó sì gbèrò ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Èbúté Èrò jẹ́ òkùn tí ó so àwọn ọmọ Ìpínlẹ̀ Èkó ayé àtijọ́ pọ̀ mọ́ ayé òde òní, Ọjà ìlú náà ni ó sì jẹ́ ọjà tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ọjà tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àdàkọ:LagosNG-geo-stub