Jump to content

Ede Angas

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ngas
Sísọ níNàìjíríà
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1998
AgbègbèÌpínlẹ̀ Plateau
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀400,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3anc
Àwọn ẹ̀yà (tan) tí ó ń sọ èdè Ngas (Angas) ní Nàìjíríà

Ẹ́dẹ̀ Ngas, tàbí Angas, jẹ́ èdè Áfríkà-mọ́-Ásíà tí wọ́n ń sọ ní Ìpínlẹ̀ Plateau, Nàìjíríà. Èdè náà pín sí méjì: Hill Angas àti Plain Angas.[1] Èdè Ngas jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè gbòógì ní Ìpínlẹ̀ Plateau, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ìkànìyàn ọdún 1952, àwọn ènìyàn Ngas ní ẹ̀yà tí ó tóbi jù lọ ní Ìpínlẹ̀ Plateau. Balogun tí ó fẹ̀yìntì, Yakubu Gowan jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Ngas.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named e18