Edgar Lungu
Ìrísí
Edgar Lungu | |
---|---|
Aare ile Sambia 6k | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 25 January 2015 | |
Vice President | Inonge Wina |
Asíwájú | Guy Scott (Acting President) Michael Sata (President) |
Alakoso Eto Abo ile Sambia | |
In office 24 December 2013 – 25 osu kinin 2015 | |
Ààrẹ | Michael Sata Guy Scott |
Asíwájú | Geoffrey Bwalya Mwamba |
Arọ́pò | Davies Chama |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1956 Ndola, Northern Rhodesia (present-day Zambia) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Party for National Development Patriotic Front (current) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Esther Lungu (m. 1986) |
Àwọn ọmọ | 6 |
Alma mater | University of Zambia |
Edgar Chagwa Lungu (ojoibi 11 November 1956) je oloselu ati ohun ni Aare ile Sambia lowolowo lati January 2015.[1][2] Labe Aare Michael Sata, Lungu lo je alakoso fun idajo ati alakoso fun eto abo. Leyin iku ojiji Aare Sata ni October 2014, Lungu je gbigba bi enialedinibo fun egbe oselu Patriotic Front.
O padanu idibo Alakoso 2021 si alatako igba pipẹ Hakainde Hichilema.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.bbc.com/news/world-africa-37086365 | Zambia's President Edgar Lungu declared election winner - BBC News
- ↑ https://www.bbc.com/news/world-africa-30970952 | Zambia Defence Minister Lungu wins presidential election - BBC News