Jump to content

Michael Sata

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Michael Sata
5th President of Zambia
In office
23 September 2011 – 28 October 2014
Vice PresidentGuy Scott
AsíwájúRupiah Banda
Arọ́pòGuy Scott (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1937-07-06)6 Oṣù Keje 1937
Mpika, Northern Rhodesia
Aláìsí28 October 2014(2014-10-28) (ọmọ ọdún 77)
King Edward VII's Hospital, London, United Kingdom
Resting placeEmbassy Park, Lusaka
15°25′19″S 28°18′34″E / 15.421884°S 28.309314°E / -15.421884; 28.309314
Ọmọorílẹ̀-èdèZambian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPatriotic Front (2001–2014)
MMD (1991–2001)
UNIP (Before 1991)
(Àwọn) olólùfẹ́Margaret Manda (?-?)
Christine Kaseba (?-2014; his death)
Àwọn ọmọ8[1]
OccupationPolice officer and trade unionist
Nickname(s)King Cobra
WebsiteMichael Sata lórí Facebook

Michael Chilufya Sata (6 July 1937 – 28 October 2014) je oloselu ara ile Zambia to je Aare ile Zambia ikarun, lati 23 September 2011 titi to fi ku ni 28 October 2014. Oloselu awujo ni,[2] o lewaju egbe oselu Patriotic Front (PF), ni Zambia. Labe Aare Frederick Chiluba, Sata je alakoso eto ni ewadun 1990 gegebi ikan lara awon to se ijoba Movement for Multiparty Democracy (MMD).


  1. Bariyo, Nicholas (29 October 2014). "Zambia President Michael Sata Dies". WSJ. Retrieved 29 October 2014. 
  2. "We are social democrats".