Edward Pwajok
Ìrísí
Edward Pwajok jẹ́ olóṣèlú omo orilẹ-ede Nàìjíríà, aṣòfin, àti Alágbàwí Àgbà. [1] [2]
Igbesi aye ibẹrẹ ati iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Edward kọ ẹkọ nípa ofin ni Yunifasiti ti Jos o si pari ẹkọ rẹ ni ile-ẹkọ ofin ti Naijiria ni Lagos. [3] O ṣiṣẹ bi adájọ́ àgbà ti Ipinle Plateau ati Komisona fún ètò Idajọ lati ọdún 2007 si ọdun 2011. [4] [5]
Ni 2015, o ti dibo si Ilé ìgbìmò Aṣoju ṣòfin, ti o nsoju àgbègbè Jos South / Jos East. [6]
Ni ọdun 2016, ile-ẹjọ ti o ga julọ ti yan an si ipo agba adajo agba ti orilẹ-ede Nàìjíríà (SAN). [7]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://dailytrust.com/lalong-has-no-respect-for-rule-of-law-pwajok/
- ↑ https://thesun.ng/jang-appreciates-pwajok-ozekhome-journalists-over-courts-victory/?amp
- ↑ https://viewpointnigeria.org/unveiling-edward-g-pwajoksan-the-deputy-governorship-candidate-of-the-labour-party/
- ↑ https://dailytrust.com/jang-s-former-commissioners-pick-reps-tickets/
- ↑ https://theeagleonline.com.ng/plateau-attorney-general-joins-reps-race/
- ↑ https://dailypost.ng/2017/05/14/pdp-crisis-hon-pwajok-dumps-pdp-week/
- ↑ https://dailypost.ng/2016/07/05/former-plateau-attorney-general-edward-pwajok-appointed-san/