Eedris Abdulkareem

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Eedris Abdulkareem
Eedris Abdulkareem at the endSARS protest in Lagos, Nigeria
Eedris Abdulkareem at the endSARS protest in Lagos, Nigeria
Background information
Orúkọ àbísọEedris Turayo Abdulkareem Ajenifuja
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kejìlá 1974 (1974-12-24) (ọmọ ọdún 49)
Kano, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Osun State, Nigeria
Irú orinR&B, African hip hop
Occupation(s)Rapper, farmer
Years active1996–present
LabelsKennis Music (? – 2005)
La Kreem Music (2005 – Present)

Eedris Turayo Abdulkareem Ajenifuja (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kejìlá, ọdún 1974) tí gbogbo ayé mọ̀ sí Eedris Abdulkareem, jẹ́ olórin ilẹ̀ Naijiria tó máa ń kọ orin hip-hop, RnB àti Afrobeat, ó tún máa ń kọ orin kalẹ̀.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíle olórogún ni a bí Eedris Turayo Abdulkareem Ajenifuja sí ní ìpínlẹ̀ Kano, ní orílẹ̀-èdè Naijiria. Ìlú Ilesha, ní ipinle Osun ni bàbá rẹ̀ ti wá, ìyá rẹ̀ sì wá láti ipinle Ogun, tí ó wà ní apá Gúúsù ilẹ̀ Naijiria, àmọ́ ó yan Ipinle Kano gẹ́gé bíi ìlú tó ti wá.[1]

Àtòjọ orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Studio albums[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • P.A.S.S (2002)
  • Mr. Lecturer (2002)
  • Jaga Jaga (2004)
  • Letter to Mr. President (2005)
  • King Is Back (2007)
  • Unfinished Business (2010)'
  • Nothing But The Truth (2020)

Singles[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • "Jaga Jaga part 2" (2012)
  • "Wonkere ft Fatai rolling dollar" (2011)
  • "Sekere" ft Vector (2013)
  • "Fela ft Femi Kuti" (2013)
  • "I Go Whoze You ft Vtek" (2013)
  • "Trouble Dey Sleep" ft Konga (2016)̀
  • "Jaga Jaga Reloaded" (2021)
  • "Oti Get E" (2021)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]