Efe Irele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Efe Irele
Ọjọ́ìbíEfeilomo Michelle Irele
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • Model
  • Actress
Websiteefeirele.com

Efeilomo Michelle Irele ni a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹsàn án.[1] Ó jẹ́ òṣèré àti aláwọ̀ṣe ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Orúkọ tí gbogbo ènìyàn mọ ọ sí ni Efe Irele.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayè rẹ àti iṣẹ́ rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Efe Irele bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aláwọ̀ṣe rẹ ní ọmọ ọdún márùndínlógún. Ó ti farahàn nínú oríṣiríṣi ìpolówó. Ó gba oyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Sociology láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Bowen àti oyè ẹlẹ́ẹ̀kejì nínú ìṣàkóso ènìyàn ( Human Resources Management) láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Chester ní Uk.[3]

Efe Irele dáwọ́lé iṣẹ́ àwòṣe fún àwọn òṣèré, ó sì tayọ nínú àwòrán fídíò ti Like to Party èyítí Burna Boy ṣe ní ọdún 2012. Ó tún tayọ nínú àwòrán fídíò ti Sade láti ọwọ́ ọ Adekunle Gold.[4] Efe ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àti eré ṣíṣẹ ti Nollywood. Lára àwọn sinimá yi ni Real Side, Chics, Wrobg Kind of war, Ire's Ire, Zahra ati Scandals.[5]

Philanthropy àti àwọn àmì ẹ̀yẹ.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Efe ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀ Efe Irele Autism ní ọdún 2018 láti ṣe ìtọ́jú fún àwọn ọmọdé autistic.[6]

Year Award Category Result
2018 City People Entertainment Awards Best Upcoming Actress of the Year (English) Won[7]
Year Award Category Result
2018 City People Entertainment Awards Best New Actress of the Year (English) Won[7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Efe Irele Biography". MyBioHub. 2017-09-28. Retrieved 2020-10-06. 
  2. "She’s a Rising Star! See Efe Irele’s Promo Shots by Kelechi Amadi-Obi". BellaNaija. Retrieved 2020-10-06. 
  3. "'Winning 2 Major Awards In One Night Is a Big Deal For Me' - Fast Rising Actress Efe Irele Tells City People". City People Magazine. 2018-09-20. Retrieved 2020-10-06. 
  4. "I Am Not Going To Expose My Body For Attention -Efe Irele". Nigeria Films. 2017-03-04. Retrieved 2020-10-06. 
  5. "I’ve a jealous lover —  Efe Irele, Actress". Vanguard News. 2018-10-20. Retrieved 2020-10-06. 
  6. "Citer". Citer. 2020-01-01. Retrieved 2020-10-06. 
  7. 7.0 7.1 Àdàkọ:Cite News