Ego Boyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ego Boyo
Ọjọ́ìbíNwakaego Nnamani
Oṣù Kẹ̀sán 6, 1968 (1968-09-06) (ọmọ ọdún 55)
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • Nigeria
Iṣẹ́
  • Actress
  • filmmaker
Ìgbà iṣẹ́1982–present
President of the International Women's Society, Nigeria


Nwakaego (Ego) Boyo (bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹsàn-án, ọdún 1968) [1]jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Anne Haastrup nínú eré Checkmate. Òun ni Ààrẹ fún ẹgbẹ́ International Women Society (IWS) èyí tí wọ́n gbé kalẹ̀ ní ọdún 1957. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Enugu. Ó jẹ́ ìyàwó fún Omamofe Boyo[2] tí ó jẹ́ ìkan láàrin àwọn adarí ní ilé iṣẹ́ Oando Plc.[3]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ego Boyo bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 1990 nígbà tí ó kópa nínú eré Checkmate. Ó bẹ̀rẹ̀ ilé iṣẹ́ tirẹ̀ tí ó pè ní Temple Productions ní ọdún 1996[4]. Ó gbé eré A Hotel Called Memory jáde ní ọdún 2017, eré náà sì gba àmì ẹ̀yẹ Best Experimental Film níbi ayẹyẹ BlackStar Film Festival ní orílẹ̀ èdè Philadephia[5]

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]