Jump to content

Egusi soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Egusi seeds without shells
Egusi soup atop a dish, with pounded yam (upper left)

Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí, tí à ń pè ní ẹ̀gúsí ní Yoruba, jẹ́ ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lu kóró èso ẹ̀gúsí gẹ́gẹ́ bíi kòṣeémáàní èròjà ọbẹ̀ náà.[1] Kóró Ẹ̀gúsí ní ọ̀rá- àti ìpínsọ̀rí afúnilókun-.ínú ẹ̀. Ọbẹ̀Ẹ̀gúsí gbòòrò ní ààrin Gbùngbùn Áfíríkàgẹ́gẹ́ bíi kòṣeémáàní wọ́n sì fi má, ń jẹ ìrẹsì, ẹ̀fọ́, ẹran sísun bíi ẹran ewúrẹ́, ẹran màlúù àti ẹja[1][2][3] A lè fi ọbẹ̀ náà jẹ eba , fufu, amala àti àwọn oúnjẹ lọ́lọ́kanòjọ̀kan àti adìyẹ. Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí jẹ́ jíjẹ ní Ìwọ̀òrùn Nàìjíríà pẹ̀lú. [4]

A máa ń se Ẹ̀gúsí nípa lílọ kóró Ẹ̀gúsí[1] :[5] Ọ̀nà méjì ni a lè gbà se ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí:

1. Ìgbésẹ̀ díndín: nípa díndín Ẹ̀gúsí lílọ̀ nínú epo pupa kí a tó fi èròjà tó kù si [5]

2. Ìgbésẹ̀ sísè: .ípa dídá Ẹ̀gúsí sínú ọbẹ̀ sísẹ̀ kí a sì jẹ́ kó sè fún ìṣẹ́jú mẹwàá kí a tó ròó pọ̀[5]

Èròjà ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí le jẹ́ tòmátì, àlùbósà, ata, àti epo, bíi epo pupa.[1][3] .ígbà mìíràn a lè lo kóró èso Ugu láti se ọbẹ̀ náà[1]

Àwọn Oúnjẹ mìíràn tó jọra

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹgúsí jẹ́ ọbẹ̀ tó gbajúmọ̀ ní ìwọ̀òrùn Áfíríkà pẹ̀lú ìyàtọ̀ díẹ̀díẹ̀ láàárín àwọn àgbègbè tí ó ń jẹ ẹ́ nípa sísè rẹ̀. Yàtọ̀ fún kóró Ẹ̀gúsí, àlùbọ́sà àti epo, ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí máa ń ní ẹ̀fó , amọ́bẹ̀dùn, àti ẹran.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]