Jump to content

Eka Soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Eka soup tí a tún mọ̀ sí ekuku jẹ́ oúnjẹ ẹ̀yà méta ní apá ìla-oòrùn ilè Nàìjíríà. Èkùrọ́, ẹ̀pà sísun àti kóró benne tí a gún ni a fi máa ń se eka soup. fufu ni ó dùn jù láti fi jẹ́.[1]

Ọbẹ̀ náà wọ́pọ̀ láàrín àwọn èèyàn Benue, Kogi àti Cross River. [2]

Benne sísun, ẹ̀pà sísun, èkùrọ́, ẹran, ẹ̀fọ́ (ewúro), maggi, àlùbọ́sà, ìsebè àti edé.

Láti se ọbẹ̀ Eka, a gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ dín ẹran fún ìṣẹ́jú díẹ̀. Lẹ́yìn náà, a máa sun kóró benne, àti ẹ̀pà súnsun, àti èkùrọ́, a sì máa lọ́ ọ́ pọ̀.[3]

Ohun tí a gún pọ̀ yìí ni a máa wá dì nídì kékèèké, tí a sì máa sè nínú epo, ewúro, àti ohun èlò mìíràn bíi maggi, àlùbọ́sà, iyọ̀, edé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́è lọ.[4]

Ọbẹ̀ tó jọ ẹka

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ọbè mìíràn tí a fi ẹ̀pà àti kóró ṣe ni:

  • Ọbè banga- èyì jé this is a delicacy of Urhobo people made from palm kernel, it is best eaten with starchy foods.[5][6]
  • Egusi soup - This is a soup made from melon seeds and leaves[7]
  • Ogbono soup - The delicacy is made cracked bush mango seeds, it is a draw soup eaten with eba, Amala.[8]

Òkèlè tí a lè fi jẹ ọbẹ̀ eka ni Eba, iyán àti fùfú.[9]

  1. "How to Make Eka Soup ( Beni seed soup)". www.onga.ng. Archived from the original on 2021-01-17. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Eka Soup (Beniseed Soup) Recipe". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-09. Archived from the original on 2021-06-25. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Eka Soup recipe Archives". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-14. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Lois (2018-03-13). "Beniseed Soup – Nigerian Sesame Seed Stew". Yummy Medley (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-01-22. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Cook The Delicious Banga Soup The Niger-Delta Way". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-19. Archived from the original on 2020-11-30. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Bring your tastebuds alive with Banga soup". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-12. Archived from the original on 2016-08-14. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Learn How To Make Delicious Egusi Soup". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-02. Archived from the original on 2022-05-28. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Ogbono Soup". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-01. Archived from the original on 2022-02-14. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "How to Make Eka Soup (Beni seed soup)". www.onga.ng. Archived from the original on 2021-01-17. Retrieved 2022-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)