Emmanuel Iren
Emmanuel Iren | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Emmanuel Aniefiok Iren |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kejìlá 1989 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Akwa Ibom, Nigeria |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals and drums |
Years active | 2008–present |
Emmanuel Aniefiok Iren (wọ́n bí ní ojo kejidinlogun osu Ope,odun 1989) tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Emmanuel Iren jẹ́ oníwàásù àti olórin ẹ̀mí ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni olùdásílẹ̀Celebration Church International (CCI), èyí tí olú-ìjọ wọn wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Nàìjíríà.[2][3] Ní ọdún 2018, ó ṣàgbéjáde orin àkọ́kọ́ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Kerygma, ní ọdún 2022, ó sì ṣàgbéjáde àwò-orin kejì rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Apostolos:Voice of Transition.[4][5]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Emmanuel Iren ní ojo kejidinlogun osu ope, odun 1989. Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ló sì ti wá. Ó lo si ile ekọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Saint Bernadettes Nursery and Primary School ní Ipaja, ní ìpínlẹ̀ Èkó.[6] Láti ibẹ̀, ó lọ sí Queen’s Choice Nursery and Primary School College ní Ikotun, ní ìpínlẹ̀ Èkó bákan náà ni o ti lo si ile iwe girama Doregos Private Academy láti kọ ẹ̀kọ́.[7]
Àtòjọ àwon orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwo orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year of Release | Title | Details | Ref |
---|---|---|---|
2018 | Kerygma
(feat Outburst Music Group) |
|
[8] |
2022 | Apostolos: Voice of Transition |
|
[9][10] |
Orin àdákọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Grace Changes Everything (feat Sinach)
- Overcome (feat E-Daniels)
- Prophetic Chant (feat Nosa)
- Fire On My Altar
- The Glory (feat Outburst Music Group)
- Yes To Your Will
Orin tó kópá nínú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àtòjọ àwọn ìwé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Leading Seeks You[13]
- Purposefully[14]
- Am I Being Fooled? FAQs about God, the Bible and Jesus Christ
- Saving Grace
- Come To Me Bible Book
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Akintomide, Marvellous (2023-06-02). "Nigerian Gospel Artists That Should Be On Your Radar". Zikoko! (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10.
- ↑ "‘We must have audacity to embrace vision regardless of culture’ says Emmanuel Iren of Celebration Church International". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-07. Archived from the original on 2023-05-15. Retrieved 2023-05-15.
- ↑ Omoleye, Omoruyi. "#YNaijaChurch100: Mercy Chinwo, Banky W, Sam Adeyemi | See the 100 Most Influential People in Christian Ministry in Nigeria". YNaija. https://ynaija.com/church100-mercy-chinwo-banky-w-sam-adeyemi-see-the-100-most-influential-people-in-christian-ministry-in-nigeria/.
- ↑ "Emmanuel Iren Features Sinach, Others In Apostolos Album". Independent Newspaper. https://independent.ng/emmanuel-iren-features-sinach-others-in-apostolos-album/.
- ↑ Rapheal (2022-10-07). "Pastor Emmanuel Iren’s Apostolos makes waves". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15.
- ↑ admin (2023-02-01). "Biography Of Apostle Emmanuel Iren". Christian Gospel songs - Christian ebooks | Christiandiet (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-26.
- ↑ Man, The New. "Biography of Apostle Emmanuel Iren". The New Man. Retrieved 2023-05-15.
- ↑ Akindele, Bolu (2018-01-17). "[The Church Blog] Introducing Kerygma: The new sound of Lyrical Theology » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10.
- ↑ Mix, Pulse (2022-08-08). "Pastor Emmanuel Iren releases his debut album 'Apostolos'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15.
- ↑ "Listen To Pastor Emmanuel Iren's Debut Album "Apostolos"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-10. Archived from the original on 2023-05-15. Retrieved 2023-05-15.
- ↑ Desk, NaijaMusic (2022-08-05). "Odunayo Adebayo ft Pastor Iren - Zoe". NaijaMusic (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10.
- ↑ S9, The Boss (2023-05-23). "Prinx Emmanuel – Bo Ta Joor Ft. Pastor Emmanuel Iren". Six9ja (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-10.
- ↑ "Leading Seeks You". Goodreads (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-15.
- ↑ "Emmanuel Iren Books. Amazon.com". www.amazon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-16.