Etikun ti Swahili

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Swahili coast

Pwani ya Waswahili  (Swahili)
Swahili coast
Coordinates: 6°48′41″S 39°17′04″E / 6.8113°S 39.2844°E / -6.8113; 39.2844Coordinates: 6°48′41″S 39°17′04″E / 6.8113°S 39.2844°E / -6.8113; 39.2844
CountriesTanzania
Kenya
Mozambique
Comoros
Major CitiesDar es Salaam (Mzizima)
Malindi
Mombasa
Sofala
Lamu
Zanzibar
Ethnic groups
 • BantuSwahili

Etikun ti Swahili jẹ etikun ti ocean ti indian ni East Africa ti awọn ẹya Swahili ngbe. Eyi lekun pẹlu Dar es Salaam; Sofala (ni Mozambique); Mombasa, Gede, Pate Island, Lamu, and Malindi (ni Kenya); and Kilwa (ni Tanzania).Óriṣiri coastal islands to wa ni Swahili coast ni Zanzibar ati Comoros[1][2].

Agbègbè ti a mọsi etikun ti Swahili ni a mọ ni adayeba gẹgẹbi Azania tabi Zingion ni igba Greco-Roman ati Zanj tabi Zinj ni Middle Eastern, Indian, and Chinese literature lati the 7th to the 14th century.Ọrọ "Swahili" tumọsi awọn ara etikun ni ede larubawa ti wọn si yọ ọrọ naa lati Sawahil("coasts")[3].

Awọn ara Swahili people ati àṣa wọn dara pọ lati ẹya ilẹ Afrika ati larubawa.Awọn Swahili jẹ olutaja ti wọn tayọ latara awọn àṣà. Etikun Swahili ni àṣa, agbègbè, ẹsin to da yatọ[4].

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigba aye tẹ̀lẹri, ki igba Swahili to ṣẹlẹ, agbegbe naa kun fun ayika to da lori oniru iṣẹ gẹgẹbi agbẹ ati owo ẹja ṣiṣe. Awọn ti wọn gbe ni etikun swahili gbẹ kẹle agbẹ ṣiṣe lori jijẹ ati mimu wọn. Nigba ti owo ṣiṣe bẹrẹ ni etikun naa, awọn oluṣowo larubawa ma nbẹnu atẹlu awọn ti kinṣe musulumi ati awọn àṣa ilẹ Afrika. Eyi lojẹ ifasẹyin fun awọn eyan jakan ti ilẹ Afrika lati ma dasi agbegbe.Eleyi lo jasi ikorajọ àṣa Swahili ati agbegbe rẹ papa eyi to da lori owo ṣiṣè[5][6]

Etikun erekusu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Óriṣiriṣi erekusu lo wa ni etiku ti swahili bi Zanzibar, Kilwa, Mafi ati Lamu. Pupọ ninu awọn erekusu yi lagbara latara awọn owo ṣiṣe. Awọn oluamọni ti wọn ni Mangroves ati Owo ẹja ṣiṣe[7][8].

Owo Ẹru[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni arin ọdun 1450 ati 1900 CE awọn eniyan million ni wọn ta ni owo ẹru si Europe, Afrika ati Asia ti wọn si gbe wọn lọ si awọn oluṣowo ẹru lati okun Mediterranean, Ọna Silk, Indian Ocean, Okun pupa ati Desert ti Sahara. Kotodi 18th century, owo oko ẹru ni east Afrika etikun kere. Awọn obinrin ati ọmọde ni wọn ma n ko lẹru ni aye Asia to ri pe wọn ma lowọn lati ṣiṣẹ ọmọ ọdọ ati Ibalopọ. Awọn ọmọ ti a bi lati awọn ẹru ti wọn ko bi Ale jẹ ọmọ ti wọn tọju gẹgẹ́bi awọn ara iyoku to yatọ si ẹru. Óriṣiriṣi ija larin awọn ẹru lo ti ṣẹlẹ ni arin ọdun 1869 ati 1883 CE ni ilu Basra, agbegbe kan to wa ni órilẹ ede Iraq. Ija awọn ẹru ni a npe ni Zanj Renellion. Ijagbara yi jasi itusilẹ awọn ẹruọ̀kẹ́ màrún-dín-ní-ọgbọ̀n, Ija naa ṣẹlẹ fun ọdun mẹerin leelogun. Awọn ẹru ti wọn to maarun leelogun lọna ẹgbẹrun doju ija kọ awọn ilu ti wọn si tu awọn ẹru ẹgbẹ silẹ lẹyin naa ni wọn ji ounjẹ ati oun ilo ogun. Ija yi lo dinku agbara ti Abbasids ni lori awọn ẹru. Nigba ija naa, awọn ẹru labẹ oludari Ali Ibn Muhammad jagun si Basra. Ọpọlọpọ awọn ẹru to kopa ninu ija naa jẹ Awọn alawọ dudu ilu Afrika.[9][10]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Cartwright, Mark (2019-04-01). "Swahili Coast". World History Encyclopedia. Retrieved 2023-08-25. 
  2. "Wonders of the African World - The Swahili Coast". Episodes. Retrieved 2023-08-25. 
  3. "The Swahili Coast and Indian Ocean Trade African Studies Center". 2022-03-30. Retrieved 2023-08-25. 
  4. "The People of the Swahili Coast". Education. 2022-06-02. Retrieved 2023-08-25. 
  5. Kordas, Ann; Lynch, Ryan J.; Nelson, Brooke; Tatlock, Julie (2022-12-14). "3.3 The Swahili Coast - World History Volume 2, from 1400". OpenStax. Retrieved 2023-08-25. 
  6. Perkins, John (2015-12-25). "The Indian Ocean and Swahili Coast coins, international networks and local developments". Afriques (OpenEdition) (06). 
  7. "About the Swahili Coast". Lazy Lagoon Island. Retrieved 2023-08-25. 
  8. Nomads, World (2020-05-15). "The Swahili Coast: Kenya’s Multicultural Lamu Island". World Nomads. Retrieved 2023-08-25. 
  9. "Wonders of the African World - The Swahili Coast". Episodes. Retrieved 2023-08-25. 
  10. Coret, Clélia (2021-10-27). "Runaway Slaves and the Aftermath of Slavery on the Swahili Coast". Journal of Global Slavery (Brill) 6 (3).