Ewéko
Plants Temporal range: Àdàkọ:Long fossil range
| |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Àjákálẹ̀: | Eukaryota |
(unranked): | Diaphoretickes |
(unranked): | Archaeplastida |
Ìjọba: | Ọ̀gbìn H. F. Copel., 1956 |
Superdivisions | |
See text | |
Synonyms | |
|
Ewéko ni irúgbìn yálà ewé tàbí igi tàbí ìtàkùn tí ó ti inú ilẹ̀ là tí wọ́n ma ń ní àwọ̀ gírín ìnì tí wọ́n ma ń fi agbara ọ̀rá àti omi inú ilẹ̀ dàgbà tí agbára ìtànṣá Oòrùn àti afẹ́fẹ́ sì ma ń fún wọn ní okun láti lè dàgbà sókè. A tún lè sọ wípé ewéko ni gbogbo ohun tí a rí tí ó ní ewé lórí tàbí lára tí kìí ṣe ènìyàn. Lórílẹ̀ àgbáyé lónìí iye ewéko tí wọ́n jẹ́ ìran àti ẹ̀yà kan náà tí wọ́n wà lórílẹ̀ agbáyé lónìí jẹ́ ẹgbẹ̀rúnmẹ́taléláàádọ́rin tí àwọn tí wọ́n ń so èso jẹ́ ẹgbẹ̀rúnméjìlélọ́gọ́ta. Ewéko ni ó gba àyè tí ó pọ̀jù lórí ilẹ̀ nítorí afẹ́fẹ́ tí wọ́n ń pèsè fún gbogbo ẹ̀dá tókù. Àwọn igi eléso tí wọ́n ń so èso bíi óúnjẹ oníhóró, èso àti ẹ̀fọ́ tí àwọn ọmọnìyàn àti ẹranko lè jẹ ni wọ́n ti wà láti ìgbà ìwáṣẹ̀. Àwọn ènìyàn ma ń lo ewéko fún onírúurú nkan tí ó wúlò fún wọn bí: ohun ìkọ́lé, ohun amúlé dára (òdòdó), ohun ìkọ̀wé àti ìwòsàn ara. Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ewéko àti bí a ṣe ń ṣe ìtọ́jú wọn ni wọ́n ń pè ní botany.
Ìpínsísọ̀rí ewéko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iye ewéko tí àwọn onímọ̀ gbà wípé ó wà ni ẹgbẹ̀rún mẹ́tàd àti méjìléláàdọ́rin,[5] ní èyí tí ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélọ́gọ́rin jẹ́ ewéko tí ó so èso tàbí irúgbìn nínú wọn ọ́ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti mẹ́tàlélọ́gọ́rin.[6] àtẹ tí ó wà nísàlẹ̀ yí fi akójọpọ̀ ewéko hàn. Oríṣiríṣi iṣẹ́ àkànṣe ni àwọn ènìyàn ti gbé kalẹ̀ láti fi má a ṣe ìwádí nípa ònkà ewéko àti irúgbìn lágbàáyé. Lára wọn ni World Flora Online.[5][7]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Cavalier-Smith, Tom (1981). "Eukaryote kingdoms: Seven or nine?". BioSystems 14 (3–4): 461–481. Bibcode 1981BiSys..14..461C. doi:10.1016/0303-2647(81)90050-2. PMID 7337818.
- ↑ Lewis, L.A.; McCourt, R.M. (2004). "Green algae and the origin of land plants". American Journal of Botany 91 (10): 1535–1556. doi:10.3732/ajb.91.10.1535. PMID 21652308.
- ↑ Kenrick, Paul; Crane, Peter R. (1997). The origin and early diversification of land plants: A cladistic study. Washington, D.C.: Smithsonian Institution Press. ISBN 978-1-56098-730-7.
- ↑ Adl, S. M. (2005). "The new higher level classification of eukaryotes with emphasis on the taxonomy of protists". Journal of Eukaryotic Microbiology 52 (5): 399–451. doi:10.1111/j.1550-7408.2005.00053.x. PMID 16248873.
- ↑ 5.0 5.1 "An Online Flora of All Known Plants". The World Flora Online. Retrieved 25 March 2020.
- ↑ "Numbers of threatened species by major groups of organisms (1996–2010)" (PDF). International Union for Conservation of Nature. 11 March 2010. Archived from the original (PDF) on 21 July 2011. Retrieved 27 April 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "How many plant species are there in the world? Scientists now have an answer". Mongabay Environmental News. 2016-05-12. Archived from the original on 23 March 2022. Retrieved 2022-05-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)