Ezra Olubi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ezra Olubi
Ọjọ́ìbíEzra Olubi
12 November 1986
Ibadan, Oyo state
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaBabcock University Illishan Remo, Ogun State
Iṣẹ́Entrepreneur,Human Rights Activist, IT expert, Chief Technology Officer, Software and Mobile App Developer
Ìgbà iṣẹ́2006-till present
Gbajúmọ̀ fúnHuman Rights Activism, LGBTIQ Advocacy, Entrepreneurship, IT, PayStack
TitleHuman Rights Activist, Chief Technology Officer, and Co-founder PayStack


Ezra Olubi tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 1986 jẹ́ olùdásílẹ̀ òwò ara ẹni, onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ (software developer) olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ paystack, àti ajàfẹ́tọ́ (born 12 November 1986 )[1].[2]

Ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ezra kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ Babcock University nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ kọmpútà ní ọdún 2006, òun àti Shola Akinlade ni wọ́n jọ pawọ́ pọ̀ da ilé-iṣẹ́ E-payment tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí PayStack sílẹ̀. Ilé-iṣẹ́ yí ni ó jẹ́ irú rẹ̀ àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú iye owó tí ó tó $120,000 àmọ́ tí ilé-iṣẹ́ Stripe padà rà pẹ́lú iye owó tí ó tó $200Million ní ọdún 2020.[3][4][2]

Ìgbé ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù kẹrin ọdún 2021, ó ṣe àfihàn aṣọ kan tí ó wọ lọ sí ibi ìgbéyàwó ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan ní oti Ìtàkùn Twitter tí àkọ́lé ara aṣọ náà sọ wípé: My friend invited me to her wedding party and all I heard was "Ezra get dressed!. Ezra yí tún jẹ́ heterosexual, ọkùnrin tìrẹẹ̀ tún ma ń kun ètè bákan náà ni ó ma ń kun èékáná pẹ̀lú. [5][6][7][8]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. October 18, Jude; Reply, 2020 (2020-10-16). "Paystack cofounder Ezra Olubi Biography, Age, Business and Net Worth". Contents101 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-03. 
  2. 2.0 2.1 Tv, Bn (2020-11-29). "Get to Know More about Paystack’s Ezra Olubi in this Interview with Peace Itimi". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-03. 
  3. "Shola Akinlade: The inspiration behind Paystack’s success". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-04. Retrieved 2021-09-03. 
  4. BellaNaija.com (2020-10-15). "Good News We Love To See: Lagos-based Paystack acquired by Stripe for $200Million". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-03. 
  5. Hoek, Jan; Tayo, Stephen; Rotinwa, Ayodeji; Lyons, Eve (2018-12-01). "What It Means to Dress in Lagos" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2018/12/01/style/nigeria-lagos-fashion-experimental.html. 
  6. Nigeria, Ripples (2021-04-18). "CELEB GIST: Paystack co-founder, Olubi, comes out as gay? Gov Buni takes Abacha’s daughter as wife number 4…more inside". Latest Nigeria News | Top Stories from Ripples Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-03. 
  7. "Twitter abuzz over Paystack co-founder's outfit to friend's wedding". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-11. Retrieved 2021-09-03. 
  8. "Nigerians react to Paystack co-founder tweet of how e 'dress' go wedding". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-56710499.