Fàájì FM
Ìrísí
City | Ìpínlẹ̀ Èkó |
---|---|
Broadcast area | Nàìjíríà |
Frequency | FM: 106.5MHz |
Owner | DAAR Communications Plc |
Sister stations | Raypower 100.5 FM |
Fàájì FM jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ kan tí ó jẹ́ ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ Daar Communications tí ó jẹ́ ti ọ̀gbẹ́ni Raymond Dokpesi jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀. Ilé-iṣẹ́ Fàájì wà ní ìlú Alágbàdo ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Fàájì FM bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ Kíní oṣù Kejìlá, ọdún 2012, tí olùdarí àgbà fún ẹ̀ka ti rédíò, ìyẹn ọ̀gbẹ́ni Kenny Ogungbe jẹ́ ẹni tí ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ẹ́fẹ́ níbẹ̀.[1][2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Faaji FM marks 3rd anniversary". TheNetng. Retrieved July 10, 2017.
- ↑ "Faaji Fm radio presenter attacked Over ‘affair’ with housewife". KemiFilani.com. Retrieved July 10, 2017.
- ↑ "Faaji 106.5 FM launches new Mobile APP". amm.com.ng. Retrieved July 10, 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]