Faiza Ibrahim
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Faiza Ibrahim | ||
Ọjọ́ ìbí | ọjọ kejìlélógún osù kẹ̀ta ọdún 1990 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ghana | ||
Ìga | ft 0 in (0.00 m) | ||
Playing position | Iwájú | ||
Club information | |||
Current club | Police Accra | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Police Accra | |||
National team | |||
2008–2010 | Ghana U20 | ||
2008– | Ghana | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Faiza Ibrahim tí a bí ní ọjọ kejìlélógún oṣù kẹta ọdún 1990 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-èdè Ghana. Ó gbá bọ́ọ̀lù ní ipò iwájú.
Ó mi àwọ̀n ní bi ayò mẹ́ta sí òdo pẹ̀lú Mali ní bi ìdíje àwọn Obìrin Afirika ti ọdún 2012.[1] Ó mi àwọ̀n ní bi ayò mẹ́ta sí òdo pẹ̀lú Etiopia ní bi ìdíje àwọn Obìrin Afirika ti ọdún 2014.[2] Ó wà nínú ẹgbẹ́ agbabọ́ọ̀lù Ghana fún ìdíje àwọn obìnrin fún ọdún 2014 [3]. Ó kúrò nínú ẹgbẹ́ ti ilẹ̀ Ghana ní oṣù keje ọdún 2015 nítorí pé ó ní ìpalára.[4][5] Ó wà nínú àwọn tí ó kópa ní Ghana fún àwọn eré Afirika ti ọdún 2015.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Black Queens beat Mali 3-0 in African qualifier - GHANAsoccernet.com". social_image.
- ↑ Michael Ofori Amanfo Boateng. "Black Queens seal Championship place – Black Queens". Archived from the original on 2017-01-23. Retrieved 2023-03-19.
- ↑ "Ghana names final squad for African Women's Championship, Police Ladies dominate - GHANAsoccernet.com". social_image.
- ↑ "Injured striker Faiza Ibrahim left out of Black Queens 18-man squad for Cameroon qualifier".[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "2016 Olympic Games qualifier: Black Queens without striker Faiza Ibrahim ahead of Cameroon showdown - GHANAsoccernet.com". social_image.
- ↑ Michael Ofori Amanfo Boateng. "Twenty-five players receive call ups as Black Queens begin camping for All Africa Games – Black Queens". Archived from the original on 2016-04-01. Retrieved 2023-03-19.