Jump to content

Fally Ipupa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fally Ipupa
Fally Ipupa (2014)
Fally Ipupa (2014)
Background information
Orúkọ àbísọFally Ipupa N'simba
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiDicap la merveille, El pibe de oro, El Maravilloso, 3x Hustler, El Rey Mago, Champions love,The king, Eagle Fally Ipupa
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kejìlá 1977 (1977-12-14) (ọmọ ọdún 47)
Kinshasa, Democratic Republic of the Congo
Irú orinNdombolo, soukous, rumba, R&B
Occupation(s)
  • singer
  • dancer
  • songwriter
  • record producer
  • record executive
  • philanthropist
InstrumentsGuitar, Vocal
Years active1989–present
LabelsF-Victeam, ROCKSTAR4000, Obouo Music, Universal A-Z
Associated acts

Fally Ipupa N'simba (ọjọ́ìbí December 14, 1977), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgé rẹ̀ Fally Ipupa, ní akọrin-akọ̀wéorin, oníjó, ọlọ́rẹ, onígìtá àti olóòtú ará Kóngò. Láti ọdún 1999 dé 2006, ó jẹ́ ìkan nínú ẹgbẹ́ olórin Quartier Latin International, tí Koffi Olomidé dásílẹ̀ ní 1986.[1]


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Archos (28 August 2014). "Fally Ipupa Decap: Biography Coming Soon". Kinshasa: Congovibes.com. Retrieved 18 April 2016.