Jump to content

Bàbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Father)
Bàbá pelu ọmọ.

Bàbá ni ọbí to je ọkùnrin eyan kan. Opolopo awon ẹranko ati eniyan ni won ni ìyá ati baba to bi won.[1][2]

Ni awon àṣà miran won pe baba ni okunrin to dagba tabi to nipo ju onitoun lo. Bakanna awon elesin Kristiani n pe ọlọ́run ni baba: "Baba wa ti n be ni orun"[3]



  1. "Definition of father". www.dictionary.com. 2019-05-09. Retrieved 2023-06-12. 
  2. "Who is a father? Here are 10 definitions we think sum him up best". The Indian Express. 2017-10-23. Retrieved 2023-06-12. 
  3. "Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?". JW.ORG. Retrieved 2023-06-12.