Fatiha Berber
Ìrísí
Fatiha Berber (odun 1945 titidi odun 2015) je esere omo ilu Àlgéríà ti atun mosi Fatiha Blal.
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi Fatiha Berber ni Casbah of Algiers.[1] A won molebi re wa lati Legata ni Boumerdès Province titi apa ariwa ilu Algeria.[2]
Ni odun 1950 okorin pelu awon Meriem Fekkaï, lehin igba na olo ko eko drama ni Conservatory of Algiers. Oludari Mustapha Gribi fun ni ipa e akoko ninu ere Molière, Les femmes savantes. Oko ipa ninu Algeria's National Liberation struggle.
O se alaisi ni ojo kerindinlogun osu kini ni odun 2015 ni pa se arun okan.[3][4]
Awon Ise
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn fiimu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Hassan Taxi, dir. Mohamed Slim Riad, 1982
- Aila Ki Nass, dir. Amar Tribeche, 1990
- Le démon au féminin [Woman as the Devil], dir. Hafsa Zinaï Koudil, 1994
- Rai, dir. Thomas Gilou, 1995
- Prima del tramonto [Before Sunset], dir. Stefano Incerti, 1999
- Aïd el-Kébir, dir. Karin Albou, 1999
Tẹlifisiọnu jara
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Cinéma: L'actrice algérienne Fatiha Berber n'est plus, Huff Post, 16 January 2015
- ↑ Yacine Idjer, Fatiha Berber: Une étoile s'est éteinte, DjaZairess, 17 January 2015.
- ↑ Cinéma: L'actrice algérienne Fatiha Berber n'est plus, Huff Post, 16 January 2015
- ↑ Yacine Idjer, Fatiha Berber: Une étoile s'est éteinte, DjaZairess, 17 January 2015.