Jump to content

Fatima Muhammad Lolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hajiya Fatima Lolo
Orúkọ àbísọFatima Muhammadu Kolo
Ọjọ́ìbí(1891-01-19)19 Oṣù Kínní 1891
Pategi, Royal Niger Company, Colonial Nigeria

Hajiya Fatima Lolo (MON), (a bí Fatima Muhammad Kolo ní Pategi, Royal Niger Company ; ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kìíní ọdún1891 – ọjọ́mẹ́ẹ̀dógún oṣù karùn-ún ọdún 1997) ó jẹ́ , akọrin, olùkọ̀wé orin, àti onímọ́ nípa ìtàn. [1]

Lolo ṣe ìgbéyàwó lẹ́ẹmejì, èyí tí kò rọ́mọ bí nínú ìgbéyàwó méjèèjì. Ó ṣe aṣojú àwọn Ìjọba Nupe ní onírúurú àjọ̀dún àti ayẹyẹ .Ṣáájú kí ó tó di olókìkì. Wọ́n mọ̀ọ́n-ọ́n nípa ṣe orin tí ó máa ń kọ fún àwọn àgbẹ̀ àti àwọn ọdẹ ní àkókò tí ó ń Jóò pẹ̀lú àbọ̀ pẹlẹbẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Lẹ́hìn ìgbà náà, wọ́n tọ́ka rẹ̀ sí Sagi Ningbazi (Olorì àwọn Ọ̀nkọrin) ní ède Nupe. Shehu Shagari ni o fun un ni MON ti Aṣẹ ti Niger. [2]

Àwọn ìọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. The Contribution of Women to National Development in Nigeria. https://books.google.com/books?id=EuC0AAAAIAAJ. 
  2. Book Now "World Nupe singer Hajiya Fatima Biography" [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Book Now Ng, 2019