Federal Government College, Ijanikin
Ìrísí
Ilé-ìwé Federal Government College, Ijanikin, jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àpapọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ girama tó wà ní Ijanikin, Lagos, Nigeria. Àjọ ìjọba àpapọ̀ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ da sílẹ̀ ní ọdún 1975.Ìdí tí wọ́n fi da sílẹ̀ ni láti ri pé wọ́n ní ọ̀kan náà lára àpapọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ girama bí ó ti wà ní àwọn Ìpínlẹ̀ méjìlá tókù ní ìjọba Àpapọ̀ náà ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ilé-ẹ̀kọ́ tó ju ọgọ́rùn-ún lọ tí wọ́n wọ́n máa ń pè ní "Unity Schools".tí Àjọ àpapọ̀ tó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ ń ṣe àbójútó rẹ̀, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Federal Unity Colleges". Federal Ministry of Education (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-03-24.